1. KÓ
NÍFÀ[1],
v
A) to
take advantage of
Ibiwumi
took advantage of Are.
Ibiwumi
kó Adé nífà.
B) to
cheat
Lola
cheated Bola because she is richer than her
Lola kó
Bola nífà nítórì ò lówo jù ú lọ
2.KÒNÍGBÀGBÉ,MÁÁNÍ
GBÀGBÉ, adj. Memorable
Monday was memorable for me
Ojọ́ ajé jẹ ojó máànígbágbé fún mí
3.KÓ
NÍJÀÁNU, v.
to control
Are
controlled himself
Adè ko
ara rẹ̀ rè nijàánu
C) to
restrain
Lizzie
restrains herself
Lizzie
ko árá rè nijàánu
4.
KÒNÍLÉ-KÒLÓNÀ, n. Vagabond
There
are lot of vagabonds here
Àwon
kònílé-kòlónà pó níbì
5.
KÓŃKO, n. The sound of a knock on the back of the hand with the shell of the
snail (ikoto)
He
knocked him with ìkòtó at the back of his hand
Ó gán an
ní konko
6. KÓNKÓ,
adj. Small
Small
food satisfies me
Òunje
KÓNKÓ lò ń yó mí.
7.
KÒŃKÓTO, KÓRÌKÓTO, n. Name of a bird (dove family)
I saw
the bird called kòríkòto
Mó rí
eiye kórìkóto
8. KÓ
PÒ, v. To gather/together
They
kept male and female together
Wón kó
àko pò mo àbo
9.KÓRÈ,
v.
A) to
harvest
We shall
harvest maize all day
À fì
gbógbó ojó kórè àgbàdo.
B) to
reap
You reap
what you sow
Ò kórè
ohún tí o gbìn
10.KÓ RÍ BÉÈ, KÓ SE, adv.
A) be it
so
She
heard her prayers and answered, May it be so
Ò gbó
adúrà rè ò sì dahùn pé, kó rí bẹ́ẹ̀
B)amen
They all
answered amen
Gbógbó
wón ní àmín
11.KÒ RÍ
BẸ́Ẹ̀, adv. By no means
It is by
no means possible
Kò lè rí
bẹ́ẹ̀.
12.
KÒRIKÒ, n. Wolf. See 'Ìkookò'
The wolf
devoured the goat
Ìkookò náà
jé ewure náà
13.KORÍKO,
n. Grass. See 'koóko'
Goats
eat grass
Ewuré máa
ń jẹ koríko
14.KÒRÍKÒSÙN,
n. A very intimate friend.
Lola and
Oyin are intimate friends
Lola atì
Oyin jẹ òré kòríkòsùn
15.KÓRÌÍRA,
v.
A) to
hate
My
mother hate lies
Ìyá mí
kórìíra iró
B) to
loathe
God
loathes sins
Olorun
kórìíra ẹ̀ṣẹ̀
16.KORÒ,
adj. Bitter
Truth is
bitter
Òtìtọ́
korò
17.KÓRO,
AKOSO, n.
A) smelting
pot
She
bought a smelting pot
18.KOORO,
adv.
A)
thorough
He has a
thorough knowledge of the subject
Ó ní ìmọ̀
tí ó yè kooro lórí iṣẹ́ náà.
19.KÒRÒFO,
n.
A)
shell(as of an egg)
I saw a
snail shell
Mó rí
kòròfo ìgbín
B)something
light
The bag
was light because it was empty
Àpo náà fúyéè nítórì kòròfo ní
20.KOROKORO,WOROWORO,
n. Brass bells out on a horse's neck as a decoration
The
children are playing with the brass bell
Awon
omodé ń fi woroworo ṣere
21.KOROKORO,adv.
A)
soundly
She
hears soundly
Korokoro
lo ń gbọ́ ọ̀rọ̀
B)clearly
To
express the Ifá oracle to the deaf, one has to recite it clearly
Korokoro là ń ránfá adití
22.KÒRÓKÒRÓ,
adv. Face to face
They saw
face to face
Wòn rí
ra kòrókòró
23.KÓRÓPÒN,WÓRÓPÒN,
n.testicle
She hit
his testicle
Ò gbá ní
kórópòn
No comments:
Post a Comment