Ẹ̀ka-èdè Ifẹ̀ ni wọ́n ti máa ń lo ọ̀rọ̀ yìí. Bí ẹni
kan bá gbé elòmíràn sépè tí ẹni tí ó gbé ẹní náà sépè bá fẹ́ẹ́ ré èpè yìí, ní
ẹ̀kà-èdè Ifẹ̀, ohun tí ẹni náà yóò sọ láti ré èpè yìí ni ‘ìkìnnìkínnì’, bí
àpẹẹrẹ,
Olú:
Ayé ẹni tí ó da omi mi yìí nù kò níí dáa.
Òjó:
Èmi ni. Ó ṣèèsì ni. Jọ̀wọ́ máà bínú.
Olú:
N ò mọ̀ pé ìwọ ni. Ó dáa náà, ‘ìkìnnìkínì’.
No comments:
Post a Comment