Sunday, 22 November 2015

Africa & Asia: Göteborg Working Papers on Asian and African Languages and Literatures



.Ọdún 2001 ni wọ́n dá Africa & Asia: Goteborg Working Papers on Asian and African Languages and Literatures sílẹ̀. Ó máa  ń gbé iṣẹ́ jade lórí èdè àti lítírésọ̀ ilẹ̀ Aáfíríkà. Èẹ̀kan lọ́dún ni wọ́n máa ń tẹ̀ ẹ́ jade. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ tí wọ́n ń ṣe ní Department of Oriental and African Languages, Goteborg University ni ó máa ń jade nínú jọ́nà yìí. Fún àlàyé ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ nípa jọ́nà yìí, ẹ lè lọ wo www.african.gu.se/aa.

No comments:

Post a Comment