brush:- (1) (ọrọ orukọ), ìgbọ́nlè
Mo fi ìgbọnlè gbọn ilé. I used brush to brush my room.
brush:-(2) (ọrọ ise) gbọ̀n; mo gbọn iyàrá mi. (I brush my room).
brute:-(ọrọ orukọ) Ìkà; ìkà náà pa ewúré mi. The
brute man kills my goat.
brutal:- (ọrọ orukọ) búburú; ọkùnrín búburú lu
iyàwó rẹ (The brutal man beat his wife).
buba:- (ọrọ-orukọ) orísìí ẹ̀wù kan; mo wo ẹ̀wù alápá gígùn. (I put on a
buba dress).
bubble:- (ọrọ-orukọ) ìru; ìrú omi isu pama. (The
bubble of water of yam quench fire).
bubble:- ru: The water inside of the pot bubbles out.
Omi inú ìkòkò ru sókè.
buck:- akọ àgbọ̀rín:- The hunter killed a buck. Ode
pa ako àgbọ̀nrín.
bucket:- (ọrọ orukọ) kete: The girl broke the
bucket (ọmọbìnrin náà fo kete omi).
buckle:- (ọrọ orukọ) ìsupò. I buckle my shoe. Mo fi
ìsupò so bata mi.
bud:- (ọrọ orukọ) òmùdọ́: the but of flower is
good. (òmùdọ́ òdòdó dára.
bud:- yọ flower buds a new leat òdòdó yọ́ ewé tuntun.
buddha:- Ìtélọ́rùn; The budha church don’t regards
worldly things (ijọ̀ ìtẹ́lọ́run ko ka ohun aye si nkan).
budge:- gbé; I budge a heavy box (Mo gbe eru títóbi).
buget:- ìsúná; The federal government made a buget for
this year. (Ìjọba àpapọ̀ se ìsúná fun odún yìí.
buffalo:- Enlá- buffalo resembles cow. (Enlá jo màlúù).
bug:- Ìdun; Idùn pò nínú iyàrá wa. Bug is too many in
our room.
bugle:- tòròmọgbè; The Night gurds use bugle to call
his member. (ọdẹ̣ fi tòròmọgbè pe àwọn elégbẹ́ rẹ.
build:- Kọ́; I will build a house. (Èmi yóò kó ile kan.
bulb:- àlùbọ́sà. My wife added a bulb to the soup.
(Iyawo mi fi àlùbọ́sa sí obe rẹ̀.
bulge:- kún; The bag of a rice is bulge (Àpò ìrẹsì
kún púpọ).
bulge:- wíwú: The way they packed the load made the
bag to bulge: (Dídì tí wọn di ẹru fa wíwú apo).
bulk:- púpọ̣: The woman bought a bulk fish (Ẹja púpọ
ni obìnrin náà rà.
bulky:- títóbi; the boy carries a bulky load. (Ẹrù
títóbi ni ọmọ náà ru).
bull:- akọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́; The bull always has power.
(Akọ kẹ́tẹ́kétẹ́ maa nn agbára).
buildozer:- katakata nlá; The contractor used
buildozer on the road construction (Agbasése lo kata kata nla fún àtúnse ojú ọ̀nà).
bullet:- Ọta; The policeman collects many bullet from
arms robbers. (Awọ̀n ọlọ́pàá gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọta lówó adùgunjalè).
bullock:- abo màlúù; The bullock has four kids. (Abo
màlúù ni ọmọ mẹ́rìn).
bully:- ẹlẹru; The masquerade are bully to women.
(Àwọn ẹgúngún jẹ ẹlẹ́rù fún àwọn obìnrìn.
bums:- tẹ̀rẹ̀; I bums inside water (Mo yọ tẹ̀rẹ̀ síun
omi).
bums:- wíwú: The head of a man still in bums until
they arrested the criminal. (wíwú ní orí ọmọ náà wa ti wọn fi mu ọ̀daràn
náà).
bun:- róbó; I took four bun to take gaari. (Mo fi róbó
mẹrin gaari).
bunch:- Padi; I bought four bunches of bananna in the
market. (Mo ra pádi ọ̀gẹ̀dẹ́ mẹ́rin ní ọtà.
bundle:- Ìgán; I have two bundles of clothes. (Mo ni
ìgàn aso méjì.
bundle:- Apáyánká; The policeman bundled the criminal
man. (àpáyànká ni àwọn ọ̀lọ́oa ọkùnrin ọ̀daràn náà).
bungalow:- Ilé ílè. My father’s house is bungalow.
(Ilé-Ìlè ni ilé bàbá mi).
bunk:- íbùsùn kékeré; I slept in a bunk bed. (Mo sun
lórí ibúsùn kékeré).
bony:- ìlapa; The fisherman paddle their canoe in the
bony. (Awọn apẹja tukọ̀ wọn lójú ìlapá).
burden:- ẹrù; I carried a burden load. (Mo gbé ẹ́rù
wíwo).
burglar:- afọ́lé; They arrested a burglar. (Wọn gba
afọ́lé mun).
burglary:- ìfọ́lé; The policemen investigated about
the burglary. (Awọn ọlọ́pàá wádìí nípa ìfọ́lé náà.
burn:- jọ́ná; this meat will burn evan yìí yóò jóná).
burn:- ìjóná egbò. The Nurse dressed a burn saw. Nọ́ọ́sí
wẹ ojú egbó ìjóná).
burners:- gbígbóná; She cooked rice with burner). Ó se
ìrẹsì pẹ̀lú ẹ̀ro gbígbóná).
‘burrow:- ihò; The rat lives in a burrow (Àwọn eku n
gbé inú ihò).
burst:- òjíjì; The children burst into laughter (òjiji
ni ẹ̀rin pa àwọn ọmọdé).
bury:- sin; They bury the dead person. (Wọn sín òkú
tó kú).
bus:- oko ero; I bought a bus. (Mo ra okà akéró kan).
bush:- igbó; the criminal hide the bush. (Àwọn ọdaran
fi ara pamọ sinu igbó).
bush farm: asálè ilè. The farmer don not like to
cultivate on the bush farm. (àwọn àgbé kìí fẹ dáko sorí asálè).
bush baby:- ọbọ
kékeré: The bush baby don’t jump: (ọbọ kekere kìí le fò).
bush fowl:- aparó. The bush fowl lives in a bush. Inú
igbó ni àparò ngbe
business:- okòwò: I am engaging myself in a business
‘ise okòwò ni mo nse.
businessman:- Ọkùnrin onísòwò: He is a businessman. O
jẹ onísòwò ọkùnrin.
busy:- ìdíwọ́ ‘I am so busy. Isẹ́ di mi lọwọ.
but:- ṣùgbọ́n. He paid but he was absect. ‘O sanwó ṣùgbọ́n
kò wá.
butcher:- alápatà: My father is a butcher: Alápatà ni
bàbá mi.
butter:- ọrá: The children like to eat bread with
butter. Àwọn ọmọ́de fẹ́ràn láti ma fi ọ̀rá jẹ búrẹ́dì.
butterfly: labalábá: butterfly has many colours labalábá
ma ni àwọ̀ orisínsíì.
button:- ìdè: My shirt has four buttons. Asọ mi ni
ìdè mẹ́rin.
buy:- rà: I bought two yams. Mo ra isu méjì.
buzz:- kùn: Àwọn oyin máa nkùn.
bwana:- ọwọ́, I give bwana to my elders. Mo fi’ ọwo
fún àwọn tó jù mi lọ
by:- tì: Come and sit by my side ‘wá jókòó tì mí.
by:- Nípa, He came by air’ Ó wá nípa okò òfurufúu.
cab:-okò ayókéléakérò; We boarded a cab. Àwọkọ̀ ayólẹ́le
akérò kan.
cab:- iwájú ọkọ̀: I sat at the cab of the vehicle. Mo
jokòó ní wájú ọkọ̀.
cabbage:- èfọ́ I ate cabbage: Mo jẹ ẹ̀fọ́
cabin:- iyàrá ìrẹjú. I slept at the cabin of the
ship. Mo sun ni iyàrá ìrẹjú ọkọ ojú omi
cabin:-ilé kékere: I built a cabin’ Mo kó ilé kékeré kan.
cabin:- inu ọkọ̀ bàlúù: The passengers sat inside a
cabin. Àwọn ero jókòó nínú ọkọ̀ bàlúù.
cabinet:- àpótí olósòó. I bought a cabinet. Mo ra
àpótí olósóo kan.
cabinet:- ìgbìmọ́, The cabinet over rule the meeting.
Awọ́n ìgbímọ ndarí ìpádé.
cable:- Okùn yìyí: They tight the plank with cable. Wọn
fi okùn yiyi so pákó.
cable:- okun iná beware of electric cable sọ́ra nípa
okùn iná.
cackle:- Kọ The cocks cackle: Àwọn àkùkọ n kọ.
cactus:- ewéko elégùn ún. I plant cactus plant. Mo
gbin ewéko ẹlẹ́gùnún.
café:- gbàgbede ìtajà, I bought salt at café. Mo ra
iyọ̀ ni gbàgede ìtajà.
cage:- ile àbò; I constructed a cage for my birds; mo kan ilé àbò fún àwọn
adíẹ mi’
cake:- àkàrà. I ate cake. Mo jẹ àkàrà.
calabash:- igbá; I ate inside calabash: Mo jeun nínú
igbá.
calcium:- amueegunle; I took calcium.
capsule:- Mo lo oògún améegunle.
calculate:- Mo ye; I calculate the number of the
block. Mo mọ iye buloku.
calendar:- iwe ìkajó; I bought 2008 calendar’ Mo ri
iwe ikajo ọdun 2008.
calf:- ọmọ màlúù. The Fulani gave me a calf. Fúlàní
fun mi ni ọmọ màlúù.
calf:- orókún: I hit my calf with table. Mọ fi orókún
gbá tábìlì.
caliph:- òlórí àwọn mùsùlùmú. Sultan is caliph of the
muslim. Sultan ni olórí àwọn Mùsùlùnú.
call:- pe. He calls me; Ó pè mí
calm:- dídákẹ́jẹ́. Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wà ún dídá kẹ́jẹ́.
came:- wá; He came last night. O wa ni àná.
camel:- Ràkúnunú. Camel always carries loads.
Ràkúnunní ma n ru erù.
camera:- ẹ̀ró ìyànwórán; I used camera to stanch the
bride and groom. Mo fi ero ìyàwòrán ya ọkọ ati aya.
camouflage:-
Dídámọ̀. The solider used camouflage drea. Àwọn ológun n lo aṣo ìdámọ̀
wọn.
camp:- àgọ́, The solider returned to their camp. Àwọn
ológun n padà si agowọn.
campaign:- polongo. The government campaign against
indiscipline. Àwọn ijọba se polongo ìwá ìbàjẹ́.
camphor:- òrí; I used camphor to rub my leg. Mo fi òrí
wó esè ma.
campus:- ogbi ilé-ẹ̀kọ́ giga: The O.A.U campus is very big. Ogba ile
ẹ̀kọ́ ti ilé-ìfẹ́ tóbi.
can:- le’ I can sleep without eating. Mo le sùn la
jeun.
can:- agolo; I bought two canst of salt. Mo ra agolo iyó méjì.
canal:- adágún; I have dung a canal; Mo ti gbẹ omi
adágún kan.
canary:- eye ayékòótó; I bought canary, Mo ra eye
ayékòọ́tó
cancel:- pare. I have cancel it. Mo ti pare.
cancer:- Jẹjẹrẹ; cancer is very serious disease.
Arunjejẹrẹ léwu pupọ
candidate:- olúdíje, One of the candidate wọn. Ọkan
nínú olùdíjè ló wo lé.
candle:- àbẹ́là, I put candle on the table, Mo gbe àbẹ́là
si orí tábìlì.
cane:- ọ̀pá. I bough two came, Mo ra òpá mejí.
cane:- egba; The students receive two stroke of cane.
Ẹgba meji meji ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ jẹ.
cane rat:- eku nlá, I killed cane rat, Mo pa eku nlá
cannie:- eyin òke-Everybody has cannie teeth. Gbogbo
ènìyàn ló ní eyin òkè.
canna:- ewékokan. I gathered canna for my pigs. Mo já
ewéko fun elédè mi
cannon:- Ìbọn nlá. The policemen carried a cannon
gun. Ibọn nla ni awọn ọlọ́pàá gbé.
cannot:- kò, I cannot do it , Emi ko ni leèsé.
canoe:- ọpọn ojú oni:- The fisherman paddled their ‘canoe, Awọn apefa ntukọ̀ opọn
ojú omi.
canopy:- àtíbàbà. There was a big canopy in front of
his house. Ati basba nla kan
wa nìiwajú ilere.
canteen:- ilé oúnje, I ate at canteen, Mo jẹun ni ilé
oúnjẹ.
canvas:- awo yíyí. I put on canvas shoe. Mo wó bata
awo yiyi.
cap:- fìlà, I put on cap. Mo de filá.
capa:- ìdérí ìgó, He covered the bottle with capa. Fi
ideri igo de ìgò
capable:- Okun:- Mo ni okun láti lọ sí ojú ogun.
capacity:- agbára. I have capacity to carry the load.
Mo ni agbara lati ko eru
cape:- erékùsù, The fisherman lives in a cape. Àwọn
apẹja ngbé erékùsù.
capital:- olú ìlú, Àbújá is capital city of Nigeria – Àbújá
ni olu ìlú Naigeria
capsidbuy:- kòkòrò, kòkòrò nmú omi obì.
capsule:- oògùn kan;
I took capsule. Mo lo oogun kan.
captain:- Balogun, My father is captain of the team.
Baba mi ni balógun ẹgbẹ́ náà.
captive :- eléwọ̀n, He was arrested as captive, Wọ́n
mun gẹ́gẹ́ bi ẹlẹ́wọ̀n.
captivity:- Ìdè ‘The man is ní captivity, Inú ide ni
okunrin náà wà.
capture:- Ségun, The policeman captured the armrobber.
Àwọn ọlọ́pàá sẹgun awọn adigun jale náà.
car:- oko ayọ́kẹ́lẹ́:- I bought a car, Mo ra ọkọ
ayókẹ́lẹ́.
car park:- Ibùdókò, I went to car park, Mo lo ibùdókò.
cavavan:- kẹkẹ, The chief rode on caravan. Olóyè gun
kẹkẹ
carbohydrate:- eroja ounjẹ agbára, Yam is
carbohydrate food, Isu jẹ ounjẹ èròja agbára.
carbon:- èédú, I brush carbon of my lantern. Mo gbọn
èédí àtùpà mi
carbondioxide:- afẹfẹamisiún , I breath carbon
dioxide, Mo fẹ afẹfẹ àmísínú.
carcas:- òkú ẹran. There was a carcas in the main
road. Òkú evan wà ní òpópónà.
card:- iwe nínípon, We use card for the student: A lo
iwe nínú p̣ọn fun akẹ́kọ́ọ̀.
cardboard:- ìwé nínú pọn: We used cardboard for the
cover book. A lo ìwé to ní pọn fun èyìn ìwé.
cardigan:- aso, otutu. I put cardigan on top of my
dress, Mo wọ asọ otútù le orí aṣọ mí
cardinal:- àlùfáà ijọ padi, The cardinal prayed for
church. Olórí àlùfàá ìjọ páádì gbàdúrà fun ìjo.
care:- tọju, They care for me, Wọn tọju mi
care:- ìtọ́jú Our Parent need care, Àwọn òbí wa ni
ìtójú.
careful:- sọ́ra. Be careful in all what you are doing,
Sọ́ra lóri gbogbo ohun to nse
careless:- àìbíkítà, Some parent are careless. Ọ̀pọ̀
àwọn òbi ni wọ́n ko bìkítà.
cargo:- érù nla. There was a cargo on the sea. Ẹrù
nlá wa lójú omi.
carnivore:- ẹranko
abèjè, Lion are carnivore kìnìní jẹ́ eranko àbẹ̀jẹ́.
carp:- orísìí ẹja kan.
carpentary:- isé owo gbénàgbénà carpentary works are
good, iṣe ọwọ́ gbénàgbénà.
carpenter:- gbénàgbénà, My father is a carpenter,
Gbéngbénà ni baba mi.
carpet:- eníàtẹ́ẹ̀ká. The spread carpet in the palace,
Wọn tẹ ẹní àtẹ́ẹ̀ká sí ààfin ọba’
carnage:- yàrá kan
nínú ọkọ̀ rélùúwéè, The railway has 20 carnages, Ọkọ rélùwée ni oguniyára.
carrot :- esokan, I ate carrot. Mo jẹ eso karọti.
carry:- rù, Mo ni eru, I carry load.
carrier:- aláànrú. The carrier carried my load. Aláàárù
ru erù mi
cast:- kẹ̀kẹ́, The solider use cent to fight. Àwọn o
jagunjagun ma nlo keke láti ja.
carton:- odidi, I bought two cartons of beer. Mo ra
odidi apoti ọtí méjì.
carvel:- gbé, I carvel a picture. Mo gbẹ́ àwòrán kan.
case:- èjo, You have a case, o ni ẹjọ́.
case:- àpò, I bough a case, Mo ra àpò kan.
cash:- owó, I collected money: Mo gba owó.
cashier:- olùkawó, Àwọn olùkawó ma nsisẹ nílé ìfowó
pamí.
cashew nut:- èso kasú. I planted cashew nut, Mo gbin
èso kasú.
cassava:- gbáàgúdá. We got gaari from cassava. A n ri
gaarí lára gbáàgúdá.
cassete:- fọ́nrán, I used cassete to record. Mo lo fọ́nrán
láti gbohùn sílẹ̀.
cassia:- Dóngóyàrò, I prepared herbs with cassia, Mo
se àgbo pẹ̀lú dóngóyárò
cast:- jù, The fisherman cast his net inside water.
Apeja ju àwọn sínú omì
cast:- àkọ́pa, he was one of the cast in the play.
Akópa ló jẹ nínú ere.
caste:- egbé ìmùlè, The caste decided not to do evil
to their member. Àwọn ẹgbẹ́ ìmùlè pinnu láti má se ará wọn ní ibi.
castle:- ilé nlá: He built a castle, Ó kọ́ ilé nla.
castor oil:- òrí, I rub my leg with castor oil. Mo fi
òrí wọ́ ẹṣẹ mi
casual:- pàjá wìrì. Mo ní àlejọ̀ pàjá wìrì. I have a
casual visitor.
casuaina :-orìsìí igi kan. I have casuarina infront of my house.
Mo ni orísìí igi kan
níwajú ilé mi.
cat:- olóngbò: Cat and mouse are enemy. Ọ̀tá ni
olóngbò àti èkúté
catalogue:- irúfẹ́. I have a catalogue of the shoe. Mo
ní irúfẹ́ àwọn bàá.
catapult:- kannkánná. I killed bird with catapult, Mo
pa ẹyẹ pẹ̀lú kannakánná.
catch:- mú, The trap catch grass cutter, Tàkúté mi mú
ọ̀yà.
catch:- pa, I catch many fishes, wọn pa ọ̀pọ̀lọ̣pọ̣̀
ẹja.
category:- ẹgbẹẹgbẹ́. The category of people
participated, ẹgbẹẹgbẹ ènìyàn ló kó pa lókópa.
caterpillar:-
tata: caterpillar eats plants. tata ma njẹ ewéko.
cathedral:- ìyá ìjo, The Auglican cathedral is at
Àkúrẹ́. Ijayọ àwọn c.m.s. wà ní Àkúrẹ́
catholic:- ìjọ kátólíkì, The catholic church worship
mary. Ìjọ́ katoliki man nsun maria
cattle:- agbo màlúù, The fulan’s always love a cattle.
Àwọn Fulani ma ni màlúù
cauliflower:- orìsíì ewékan. The cauliflower is good.
cause:- fa: ọkùnrin onikèkẹ́ ló fa ìjàmbá.
cause:- olùfá Baba wale was the cause of fighting.
Baba wale ni olùfà ìjà.
cause way:- orísìí ọ̀nà kan. There a lot of causeway in the major
road.
caution:- ìsọ́ra, You must be caution. O gbọdọ̀ ni
ìsọ́ra.
cavalry:- ẹlẹ́sin ológun, ẹlẹsín ológun ni awọn akọgun,
The warrior is always cavalry.
cave:- Ihò àpáta. The snak hide inside cave. ejo ma
nsa si inu ihò àpátà.
cease:- dáké. The storm cease. Ìjì dákẹ́
ceaseless:- ọ̀dá- ọ̀dá òjò ko dára, ceaseless is not
good.
cedar:- orísìí igi kan, I have a cedar in my house. Mo ni orísìí igi kan ni ile mi.
ceiling:- àjà. I have coverall my ceiling a. Mo ti bo
àjà mi.
celebrate:- Yò, I celebrate with her. Mo bá à yò.
cell:- ẹ̀wọ̀n, The criminal are ni cell. Àwọn ọ̀danànwà
ní ẹ̀wọ́n
celebration:- ajọyọ, The celebration birthing of my
wife is next week. Àjọyọ̀ ọ̀jọ́ ìbí iyàwó mi di ọsẹ tó nbọ̀
cellar:- àká, I built cellar, Mo kó àká.
cellophane:- ọ̀rá:- The clothes are in cellophare! Aṣọ
wà nínú ọ̀rá
cellulose:- orísún eweko
cement:- ìyẹ̀fun ìkọ́lẹ́. I bought 2 bags of cement.
Mọ ra àpọ̀ iyẹfun kọ́lá méjì.
cemetery:- Ilè ìsùnkú. The man was burial in cemetery.
Wọn si baba náà sí ilẹ isunku
censor:- àwòfín, The commission censor the play before
it acts, Àwọn igbimọ wọn se àwòfún ere náà kótó di sísè.
cent:- owó cent are curreney of a particular country. Owo sient jẹ mo orile ede kan.
census:- kíka ènìyàn, The Nigeri’a censor was 2006.
Kíká ènìyàn Najiria waye ni 2006.
certiprade:- dídíwọ̀n ìgbóná.
centimeter:- òdiwọ̀n gigun. The height of a chair is
30 centimeter. Giga aga to ọgbọn ìgbọ̀wọ́.
centipede:- ọ̀wáwà. The centipede a enemy to farmer. Ọ̀wawà jẹ ọ̀tá si agbẹ̀.
centre:- gbàgéde:- The met at center of the town. Wọn
pade in gbàgede ìlú.
century:- ọgọ́rùn ọdún. My father had died almost a
centry ago. Baba mi ti ki to ọgọrun ọdun
ceremies:- èlò amò. Potters deals with cerement.
Amokoko ni ìbase pẹ̀lú elo amọ .
cereal:- irúgbìn kan. I planted a cereal plant. Mo gbin
irugbin kan.
ceremony:- àjọyọ̀, I have a ceremony; Mo ni àyoyò kan.
certain:- dájú, it is certain, he will not come, Ó
dájú pé kò ní wá.
certificate:- ìwé eri, I have get my certificate, Mo
ti gba ìwé ewi mi.
chaff:- ìgboyàn, I remove chaff from corn, Mo fẹ́
ìgbajàn àgbàdo.
chain:- okùn, I tight it with chain; Mo fi okùn irin
dèé.
chain:- dè, I tight him. Mo dèé.
chair:- àgá, I sit on a chair. Mo jókòó lórí àga.
chairman:- alága. He was a chairman, ó jẹ́ alága.
chalk:- ẹfun, Teachers use chalk. Àwọn olùkó n lo ẹfun.
challenge:- ìpèníjà, He challenge me, ó pè mi ìpèníjà.
chameleon:- Ọgà, n pa àwò dà.
champion:- Olùborí, I am champion. Mo jẹ́ olúborí.
chance:- ààyè. I have chance. Mo ni ààyè
chancellor:- Olórí ile iwe yunifasiti. He is a
chancellor, ó jẹ́ olórí ilé-ìwé Yunfáátì.
change:- yípádà, He change for bette, O yipada si
dáradára.
channel:- là, He channel water to other part, ó le
ojútò omi si ibòmíràn.
channel:- ojútò omi, There is a channel of water at
back of my house. Ojútò omi wa ni ehinkule mi.
chant:- sun, He chants ìjàlá, Ó sun ìjálá.
chant:- Igbe- He heard a chant, ó gbọ́ igbe kan.
chapel:- ibi ìjọ́sìn. We have a chapel in our school,
A ní ibi ìjósùn ni ilé iwe wa.
chaplain:- olùdarí ile ìjọ́sùn. My father is chaplain.
Baba mi jẹ olùdarí ilé ìjọsùn.
chapter:- ori ìwé, I opened a chapter, Mo si ní ìwé kan.
character:- àbúdá, He has a bad character, Oni àbùdá
búburú.
character:- akópa, He is one of the character. Ó jẹ́ akópa.
char coal:- èédú, I dry my charcoal. Mo sa èédú mí.
charge:- díye, I charge, Mo díye.
charge:- físùn. They changer him, wọn fẹ̀sùn kàn án.
charity:- ẹsọ charity begins at home, Ilé làátí ko
èsó lo òde.
charm:- là. The young girl charmed all ọmọbìnrìn la
gbogbo wọn.
charm:- ìtẹ́lọ́rùn:- The man had a great charm, Ọkùnrin
náà ni ìtẹ́lọ́rùn.
chart:- awọran ibikan. The captain was looking at his
chart. Ọ̀gágun n wo awòrán ibikan
chase:- lé, He chase dog. Ó lé ajá.
chase:- lílé, He caught him after a long chase, o gba
mun ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ lílé.
chassis:- odidi ara mọ́tò. The mechanic s is repairing
to the chassis of my car. Atúnkọ̀se n se àtúnse se odidi are mótò ni.
chat:- àwàdá, I chat with him, Mo se àwàda pẹ̀lú rẹ.
chatter:- siseawada. The little girls were chattering.
Awọn ọlọmọbínrin n àwádà.
cheep:- dínwó, The fish is cheap, Ẹja náà dínwó
cheat:- tanjẹ. Ó tànjẹ, He cheats him
cheat:- Olùtànjẹ. The fish seller is a cheat, Ẹlẹ́ja
jẹ olùtanjẹ́.
cheek:- wó, He cheeks the drives. Ó wo awàkọ̀.
cheek:- ẹ̀rẹ̀kẹ́, He tonehes her cheek. O ti awọ
kanan ni ẹ̀rẹ̀ké.
cheeky:- àìníọ̀wọ̀, cheeky is not good. Ainiọwọ ko
dára.
cheer:- ìdáraya, The children laughter cheered up the
old woman erin ọmọde ma mun ìdáraya fun awọn
arúgbó.
cheese:- ounjẹ láti are wara, I took cheese. Mo jẹ
ounjẹ ara wara.
cheetah:- orísìí aisan kan kan
fun olóngbò.
citizens:-ọmọ orílẹ̀, I am a Nigeria
citizen, Mo jẹ ọmọ orilẹ Naijiria.
cheque:- sòwédówó. He gave me a chegue. Ó fùn mi ni
sòwédowó.
chest:- àyà, cover your chest. Da aṣọ bo aya rẹ.
chest:- àpósí ìsúra, I have a chest: Mo ni àpótí
ìsúra.
chew:- jẹ, I chew coconut, Mo jẹ obì
chewing stick:- orín, I have a chewing stick, Mo ni
orin.
chick:- òròmodìẹ, I a bought a chick, Mo ra òròmọdìẹ.
chicken:- adìẹ, Mo ra adiẹ mẹ́fà, I bought six
chicken.
chicken pox:- àrùn ìgbọ́na: Chicken pox is very deadly
disease. Orin ìgbóná jẹ arun afiku pani.
chief:- pàtàkì: Àwọn ìlú pàtàkì ni ilẹ Nàìjíríà ni ìbàdán
ati Èkó.
chief:- olóyè, My father is a chief. Baba mi jẹ
olóyè.
chieftain:- olórí olóyè, The chieftain is very high
post. Olórí oloye se pàtàkì.
child:- ọmọdé, I have a child. Mo ni ọmọ
childhood:- ìgbà èwe, I have experienced childhood. Mo
ti fi igba kan
jẹ èwe.
childish:- ìwà ọmọde. It is childish idea, o jẹ ìwà
ọmọdé.
chime:- lù, It is chime 3 o’clock, Agogo lu mẹ́ta.
chime:- ìgbe agogo wọn gbọ igbe agogo. They head’
the chime of the bell.
chimpanzee:- ìnàkí ìnàkí jẹ ẹranko to lágbára.
chin:- àgbọ̀n, Mo fa irugbọ̀n mi, I salv my chim.
chip:- akufọ. The chip of the bottle is very
delicate. Àkúfọ́ igo léwu.
chip:- anamọ dindin. I ate chip, Mo jẹ ánámọ̀
díndín.
chip:- fó, Awo ounjẹ fọ lọ́wọ́ mi. The plate chip
off.
chirp:- dún. The bird chips, Eye dún
chisel:- ohun elo ti àwọn onísọ́nà n lò.
chocolate:- ìyẹ̀fun mimu, I took chocolate, Mo mun
ìyèfun.
choice:- tire; I like her choice, Mo fẹ tirẹ
choir:- Akorin. The choir sang song, Àwọn akorin kọrin
choke:- àìmí, I choked because a fish bone was stuck
in my throat, àìmí fa egun tó gún mí lórùn.
cholera:- àìsàn onígbáméjì, cholera are very dangerous
disease, àìsàn onígbéméjì léwu.
choose:- yàn, I choose to do Yorùbá instead of
English. Mo yàn láti se Yorùbá dípò èdè òyinbó.
chop:- gé, I chopped vegetable made pot. Mo ge ẹfọ
sinu ikòkò.
chop:- ẹya ara ẹran, I cooked chop meat. Mo sé eya
àrà eran
chorus:- orísìrísìí órin. There were a lot of chorus
sang in the church, Wọn kọ orísírìsíì orin ni sọ́ọ́sì.
christens:- fun ni orukọ igbagbọ, I gave him a
christen name. Mo fun mi orúkọ
ìgbàgbọ́.
christian:- onígbàgbó. Christain and Moslem dominated
the college. Onígbàgbọ́ àti Mùsùlùmí ni wọn pọ ni ile-ẹkọ giga.
christmas:- ọjọ ibi Jesu, December 25th
of every year is Christmas. Ọjọ karundinlọgbọn jẹ ọjọ ibi Jesu.
chrysalis:- lántete; Chrysalis become butterfly. Lantete
lo n di labalábá.
chukle:- rẹ́rìn músẹ́, He chuckles while reading, Ó rẹ́rùn
musẹ bó n se nkàwé.
chuckle:- ẹ̀rín músẹ́, He saw chuckle, o rip e o rẹ́rìn
músẹ́.
church:- Ile ijọsun, I went to church, Mo lọ ilé ìjọsùn.
cigar:- ewé taba ti a di papọfún mímun.
cigarette:- sìgá, he smokes cigarette, Ó mu sìgá.
cinema:- sinnimọ. There will show in cinema house. A
ó fi awórán hàn on ilé sinmimọ́.
circle:- pagbo, The children circle round the field.
Àwọn ọmọ pagbo gi papa ka.
circular:- iwe ifilo, The circular was sent to him. A
fi ìwé ìfilọ ransẹ sìí.
circulate:- kárí, The blood circulate the body ẹjẹ
kárí ara.
circulation:- káàkiri: Circulation of the blood, ìrin
káàkkíri ẹ̀jẹ̀
circumstance:- Sábàbí, What is your circumstances of
your divorce. Kinni o fa sababi ìkòsílẹ̀.
city:- Ìlú- Akurẹ is a city, Akúrẹ jẹ ìlú nlá.
civet:- kòlòkòlò, civet killed my chicken. Kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀
pa adìẹ mi jẹ.
cavies:- ojuse ati eto ènìyàn, Government deals with
cavies. Àwọn ijọba nsètò lórí ojúse.
civil:- olótító. Be civil to your husband jẹ olotitọ
si ọkọ rẹ
civilian:- ólósèlú, civilian is better then military,
ìjọba olósèlú dára ju ológun.
civilize:- láju, Awa náà ti laju, We have civilized.
civilization:- ọ̀làjú civilization has come to Nigeria. Ọlaju
ti de si Nàìjíríà.
claim:- bere fun, I claim my money, Mo beerd fun owó
mi.
claim:- owó ètó, The worker asked for their claim. Àwọn
osisẹ bere fun owo ètó.
clam:- ẹranko kan
nínú okun, An animal inside the sea.
clan:- ìrandíran, our clan migrated from Ire, Iràn wá
sẹ̣̀ láti Ìré
clang:- ki irin lurawọn.
clap:- pàtẹ́wọ́, The children clapped their hands. Àwọn
ọmọde patewo.
clap:- pípàtẹ́wọ, Clapping of hand motivate actor.
Pipetẹ́wọ mun ori osere wu.
clash:- fìjapẹẹta:- The policeman clashed with
students; Àwọn ọlọ́pàá fìjàpẹ́eta pẹ̀lú akẹ́kọ̀ọ́.
chash:- forisanpọn:- Neco examinations has clashed, Ìdánawò Neco
forísánpọ́n.
clasp:- dìímú, He clasps it, ó dìímú.
clasp:- di, I clasp it with rope, Mo di pẹ̀lú okùn.
class:- iyàrá ìkáwé. The government built 2 classroom.
Ijọba kọ iyara ìkáwé méjì.
classify:- Pin, I classified it into two. Mo pin si ọ̀nà
méjì.
classification:- ìpín: What clasifcation do you belong.
Ìpín wo ni tìrẹ.
clatter:- ariwo n lá, I head a clatter sound. Mo gbọ́
ariwo nlá
clause:- odidi awẹ́ gbólóhùn, The sentence is clause
claw:- eekanna-ẹyẹ, Bird has claw, Ẹyẹ ni èékánná
clay:- ámọ̀: I mould pot with clay, Mo mo ìkòkó pẹ̀lú
amọ̀.
clean:- mimọ, The room was clean. Iyàrá náà mo.
clean:- fọ, I clean my room. Mo fọ iyárá mi;
clear:- yé, It is clear, Ó yé
clear:- gbá, I clear the rubbish, Mo ti gba ìdọ̀tí.
clergyman :- òjísẹ́ ọlọ́run. My father is clergyman.
Baba mi jẹ òjíṣẹ́ ọlọ́run.
clerk:- akọ̀wé, The clerk gave me receipt, Akọwe fun
mi ni iwe ẹri pe mo raja.
clever:-
jáfáfá, He is clever, ó já fáfá.
click:- mun, I click it, Mo mún un.
cliff:- gegele, He lives at chiff, o n gbe ibi gegele.
climate:- àkókò, The climate is good. Akoko yii dara
fun igi.
cling:- so, She clings to her mother, Ó sọ mó ìyá rẹ̀.
clinic:- ilé ìwósán, He took his son to clinic, O gbe
ọmọ rẹ lọ ilé ìwósàn.
clip:- okun irin, He tight it with clip. O fi okun
irin so pọ
clip:- lẹ, It clips together, Ó lè mọ ara wọn.
clippers:-
clock:- agogo, I bought a clock. Mo ra agogo.
clockwise:- owó ago:- One of my clockwise has removed,
ọ̀wọ́ ago mi ti bọ́.
close:- tì, I closed the door, Mo ti ìlẹ̀kùn.
close:- itòsí: My house is very close, Itòsí ni ile mi
wa.
clot:- dì, The blood is cloth, èjè náà dì.
closh:- aṣọ: I bought a cloth. Mo ra aṣọ.
cloth weaver:- Ahunsọ: My father is cloth weaver.
Baba mi jẹ ahunsọ
clothing:- ilé aṣọ́ síse. I went to clothing – Mọ lọ
ile aṣọ síse
cloud:- ìkúùkú, There was a cloud ìkúùkù wa.
cloudy:- kùrukùru, The sky was cloudy. Kùrukùru gba
sánmọ.
clove:- omudo òdòdó, I love clove, Mo fẹ́ràn òmòdó
òdòdó.
clown:- ‘egbé’̣, I am a member of rotary blub. Mo jẹ
ọmọ ẹgbẹ́ àánu.
club:- kùmọ̀, I used club to kill snake. Mo ló kùmọ̀
láti pa ejò.
clue:- àbágo, I have seen clue, Mo ti ri ọ̀nà àbáyọ.
clumsy:- súnmọ́, It seems clumsy, Ó dàbí pe ó sún mọ.
clutch:- sísọ: He Clutch to the rope, síso ni o so mo
okùn.
coach:- Iyara oko rélùwéè, I sat in a coach. Mo jókòó
nínú ọkọ̀ rélùwéè.
coach:- olukọ ere ìdáráya. I am football coach. Mo jẹ
olukọ ere agbá bóólù.
coal:- èédú, Don’t touch that coal, Máse fi ọwọ kan èédú
coal field:- Ilẹ-èédú, Enugu is a coal field. Enugu jẹ ilẹ èédú.
coarse:- bàíbàí, Your cloth is coarse. Aṣọ rẹ ri
báibai.
coast:- èbíté, The fish man rested in the coast. Àwọn
apẹja sinmin ni èbúté.
coastal:- agbégbéomi ìlú awọ́n jẹ́ agbègbé omi. Their
town is coastal area.
coat:- aṣọ ìlékè, I put on coat on my dress. Mo wọ
aṣọ ilékè sí aṣọ mi.
coat hanger:- agbásodúró:- I have a coat hanger. Mo ni
agbásodúró.
cub:- háhá àgbàdo, I remove maise cub. Mo yah aha
àgbádo.
cobbler:- asobàta, The cubbler repaired my show.
Atunbata se bata mi.
cobra:- ejò oká. I killed cobra. Mo pá ejò ọká.
cobweb:- Ilé alántankù, There was cobweb in my house,
Ile alantankan wa ni ilé mi.
cock:- àkùko adíẹ, I killed a cock for chritmas
celebration, Mo pa akukọ fun ayẹyẹ ọdun
cockerel:- ako òròmodíẹ̀, I have six cokerel. Mo ni akọ
òròmodíè mẹ́fà.
cocoa:- kòkó. I have a cocoa farm. Mo ni oko kòkó.
coconut:- àgbọn. I planted coconut at my house: Mo
gbin àgbọn síwájú ilé mi.
coconut oil:- epo àgbọn, women sell epo agbọn. Awọn
obìnrin nta epo agbọn.
coconut palm:- igi àgbọn, coconut palm always tall.
Igi agbọn naa ga.
cocoon:- ẹlẹ́ta, cocoon becomes bulterfly, ẹléta
ndi labalábá
cocoyam:- kóókò, cocoyam is sweet, isu koko ma n dùn
cod:- ẹja kan,
cod is sweet. Ẹja kọdu máa n dún.
coffee:- ìyèfun mímú. I took coffee, Mo mun ìyẹ̀fún.
coffee:- pósí, coffin is always use for dead. Wọn fi
posi sín òkú.
coil:- kájọ. The snake coiled. Ejò náà kájọ.
coil:- kíkájọ, They coiled together, kíkájọ mi wọ́n
ká.
coin:- owo sílè, He gave me coin. Ó fún mi ni owó
sílè.
cold:- tutu, The food was cold. Oúnjẹ náà tutu.
cold:- ótútù, I have cold. Mo ni otútù
collapse:- wó, The building collapsed, Ilé ti wó.
collar:- ìdé, There was a collar at my dog’s neek. Ìdè
wá ní orùn aja mi.
collect:- gbà, He collect from me. Ó gbàa lọ́wọ́ mi.
college:- Ilé èkó gíga, I went to college, Mo lo ilé ẹ̀kọ́
gíga.
collide:- fóríso. Wọn forísọ ara àwọn, They
collided together.
collision:- ìforísọ: There was collision with two
vechiles, ìforísọ wáye láàrin ọkọ̀ méjì.
collon:- ami to sáájú apẹẹrẹ, the writer used
collon. Ònkọ́wé lo ami to sáájú apẹẹrẹ.
colonel:- Ògágún. My father is colonel, Baba mi jẹ ọ̀gágun.
colonize:- sàkóso. The British colonize Nigeria. Àwọn
Gẹ́ẹ̀sí sàkóso ilẹ Nàíjíríà.
colonization:- ìsàkóso, Colonizat started 150 years
ago: Ìsàkóso bẹrẹ ní àádọ́jọ ọdun.
colony:- abẹ́ àkósó, Nigeria was under British colony.
Nàíjíríà wa ni abé àkóso ilẹ̀ Gèésì.
colonialism:- ìgabalé, The African leaders fought
against colonialism. Àwọn olóri Aafirika jà fitafita lori ìgàbalé.
colour:- àwọ̀, I have a black colour shoe, Mo ni àwọ̀
bàtà dúdú.
colourful:- àwọ̀ pípò, I have a colourful clothes. Mo
ni àwọn àwọ̀ aṣọ tó pò.
colour:- kùn, I colour my picture, Mo kun àwòrán mi.
colt:- akọ ẹsun. The colt run fast, Akọ ẹsin ma
ngáré.
column:- òpó, there was column in the building, òpó wa
nínú ilè.
column:- ààyé, There was a column. Ààyè kán wà.
comb:- òòyà. I have a comb. Mo ni òòyà.
comb:- ya. Mo ya ori mi, I comb my hair.
combine:- papọ̀, Two houses combin together. Ilé méjì
papọ̀.
combination:- ìpapọ̀, Their combination brings unity.
Ìpapọ̀ wọn fa ìsọ̀kan
come:- wá, He has come. Ó ti wá.
comedy:- apanílẹ̀rín. The play was comedy ere náà jẹ apanílẹ̀rín.
comet:- irawọ kékeré.
comfort:- ìtùnú, He gives me comfort, Ó fún mi ni
ìtùnú.
comfort:- tùnínú, He comforts me. Ó tù mí nínú.
comfortable:- tù mí, I am comfortable, Ara tù mí.
comic:- àwàdà, I watched a comic play. Mo wo ere àwàdà
comma:- ami ìdánudúródíè, There was a comma, Ami
idanuduro wà.
command:- pàsẹ, I command to bring him. Mó pàsẹ pé
kí wọ́n mún wá.
commander:- (aláse, I become commander, Mo di alásẹ̀.
commander in chief:- Olóri aláse, My father is
commander in chief, Baba mi jẹ olórialáse.
command:- àsẹ, They obey his command, Wọn tele asẹ
rẹ
commandment:- ofin, There were ten commdment. Ofin mẹ́wàá
ó wà.
commet:- dásì, He commets, ó dásì
commentator:- olùsọ nípa nkankan. There was football
commentator. Olusọ ere bọ́ọ̀lu.
commercial:- ètò okòwò, He deals with commercial
business, Isẹ́ rẹ jẹ mọ́ ètò okòwò.
commissioner:- alákóso. He is a commission. Ó jẹ́
alákóso.
commit:- sàìdára. The child commits. Ọmọ náà
sàìdára.
commitment:- Ojúse, I have many commitment, Mo ni ojúse
tó pọ̀.
committee:- Igbimọ, He is a member of committee, Mo
jẹ́ ọmọ ìgbìmọ̀.
commodity:- nkànkan, I bought a commodity, Mo ra
nkankan.
common:- wọ́pọ̀, Poverty is common in Nigeria, Òsì wọ́pọ̀
ni ilẹ̀ Naijiria.
common weath:- Awọn àkójọpọ̀ orilẹ èdè tó gbá
òmìnira lọ́wọ́ ìjọba Gẹ́ẹ̀sì, Nigeria
is one of common weath of nation. Naijira jẹ okan lára orilẹ èdè to kuro lọ́wọ́
ìjọba Gẹ́ẹ̀sì.
commincate:- sọ, Comminicate to your students, ba awọn
akẹ́kọ̀ọ́ rẹ sọ.
communication:- sisọ, Commication is good. sísọ ló
dára.
communion:- ara oluwa, Christain take communion. Àwọn
onigbàgbọ́ ngbara olúwa.
community:- àdúgbò, There was a piece in my community,
Alaafia wa ni àdùgbò mi
campanion:- ara, You are my companion. O jẹ ara mi.
comparative:- yíyàn, There was comparative study, Àwọn
yíyàn isẹ wa.
compare:- wosakun. I compare Tunde and Ayọ. Mo
wosakan Tunde àti Ayọ.
compass:- ẹrọ ìsamọ̀nà. The pilot use compass, Awakọ
bàlúù n lo ero ìsamọ̀nà.
compel:- kànnpá, The police compel him to follow
them. Àwọn ọlọ́pàá kànnpá fun láti tẹ̀lé wọn.
compete:- díje, He want to compete with me. Ó fẹ díje
pẹ̀lú mi
competition:- ìdíje. The student particitipate in the
competition. Àwọn akẹ́kọ̀ó kópa nínú ìdíje.
complain:- sàròyé. The driver complained about bad
money. Awakọ̀ sàròye nípa owó ti ko dára.
complete:- parí. I have completed my work. Mo ti parí
isẹ́ mi.
complexion:- àwọ ara; I have black.
complexion:- Mo ni àwọ̀ dúdú.
complicated:- sòro, the work is very complicate. Isẹ́
náà sòro.
compliment:- ìkini. compliments of the season, Ẹ kú ọdún.
compose:- kọ, I compose a song, Mo kọ orin.
composer:- olùkọrin, she is a composer, Ó jẹ́ olúkọrin.
composition:- àròkọ, The student wrote a composition
on the food I like best. Àwọn akẹkọọ kọ àròkọ lórí oúnjẹ tí mo fẹ́ràn.
compost:- ajílẹ̀, The compost is good for planting
ajílẹ̀ dára fún ohun ọ̀gbín.
compound:- àyíká, My school compound is good. àyíka
ile-ìwé mi dára.
comprehension:- àkàyé, I have a work on comprehension.
Mo ni isẹ́ lórí àkàyé.
compulsory:- dandan, Tax is compulsory in my state,
owo ori kan
dandan ni ìpínlẹ̀ wa.
computer:- ẹrọ ayára bi àsá. The government gave us
four computers set. Àwọn ìjọba fún wa ni ẹrọ ayárabi àsá mẹ́rin.
concern:- nítara. I have concern on her. Mo nítara fún
un.
concert:- idije orin, I have music concert, Mo ni
ìdíje orin.
conclusion:- ìparí, In conclusion, Ni ìparí.
condemn:- jẹ niya, He was condemn to die, Wọ́n jẹ́
níya pe kó kú.
condition:- ipò. I have a bad condition, Ipò mi ko
dára.
conduct:- se. I conduct test for the students. Mo se
ìdánwò ranpẹ fun àwọn akẹ́kọ̀ọ́.
conduct:- ìwà, The students conduct is bad. Ìwà àwọn
akẹ́kọ̀ọ́ ko dara.
cone:- sónsó.
contradict:- tàkora, His explanations was
contraducted, alaye rẹ takora wọn.
contray:- ìdàkejì, It is contray to his opinion, O jẹ
ìdàkẹjì sí èrò rẹ
contribute:- dá, He contributed to development of the
house. Ó dá owo fun ìdàgbàsóke ilé.
contribution:- mọ̀dámọ̀dá, They gave him his
contribution. Wọn fun ni owo mọ̀dámọ̀dá.
control:- sàkóso, I am controlling, Mo nse sàkóso.
converment:- ìtẹ́lọ́rùn, I am converment, Mo ní ìtẹ́lọ́rùn.
conveniencse:- ìrọ̀rùn, It is very convenience, for
me. Ó jẹ́ ìrọ̀run fun mi.
conversation:- I have a little conversation. Mo ni ọrọ
kékeré láti bá ọ sọ.
convert:- yi, I have converted to christain, Mo ti yi
si Kirisitẹni.
conversion:- yíyí, They made a conversion. Yìyí ni wọn
yí.
convey:- gbé, He conrey it to the market. Ó gbé lọ sí
ọjà.
convey:- ki, Convey my greeting to your wife. Kí ìyáwó
rẹ fún mi
convcelt:- òdaràn, The convcelt ran from the prision,
Ọ̀daràn náà sa kúrò ni ọgbà ẹ̀wọ́n.
convince:-yí, I convince him, Mo yí padà.
cook:-se, I cooked rice, Mo se ìrẹsí.
cook:- alásè, The cook cooked food. ‘Alásè se oúnjẹ.
cooker:- ẹrọ aseoúnjẹ, I used cooker to cook rice.
Mo lo ẹrọ ase ounjẹ láti se ìrẹsì.
cooking oil:- òróró, I used cooking oil to cook rice,
Mo lo òróró láti se ìrẹsì.
cooking pot:- ìkòkò, I bought cooking pot. Mo ra
ìkòkò.
cool:- tutu, I like cool water. Mo fẹ omi tutu.
co-operate:- fọwọsowọ́pò, she co-operate with his
husband, O fọwọsowọ pọ̀ pẹ̀lú ọkọ rẹ.
co-operation:- ìfọwọ́sowọ́pọ̀. Co-operation brings
unity, Ifọwọsowọpọ nfa ìsọ̀kan.
co-operation:- egbẹ́ alajésékù, I am member of
co-operation. Mo jẹ́ ọmọ egbe alájẹsẹ́kì.
copy:- ẹ̀dà, I have a copy, Mo ni ẹ̀dà.
coral:-orísìí kinníkan,
cord:- okùn, There is a cord in my dog’s neck, okun wà
ní orun aja mi.
cork:- ìdérí ìjò ‘They cork it. Wọ́n dée.
corm:- irúfẹ́ ohun ògbin kan.
corn:- ọmọ àgbàdo, I planted a corn, Mo gbín ọmọ
àgbàdo.
corner:- igun ilé. I put a table at the corner of my
house. Mo gbé tábìlì si igun ilé mi.
corporal:- ọmọ ogun. He is a corporal, o jẹ ọmọ
ogun.
corporation:- àjùmòse, He is a member of corporation.
O jẹ ọmọ egbé àjùmọ̀se.
corpse:- òkú. They saw a corpse. Wọn ri òkú.
correct:- atunse. I did a correction, Mo se àtúnse.
correspond:- kíkọ
corridor:- ọ̀nà tó gbá inú ilé kọjá. Pass that
corridor, Gba ọ̀nà yẹn.
corrupt:- àbẹ̀tẹ́lẹ̀, He is corrupt, Ó n gbá àbẹ́tẹ́lẹ̀:
corruption:- ìwà àbẹ̀tẹ́lẹ̀. They set him to prison
because of corruption. Wọn ran lo sewọn nítòrì ìwà àbẹ̀tẹ́lẹ̀.
cosmetics:- ohun èlò ìsara lọ́sòó. Women use
cosmetics. Àwọn obìnrin n ohun èlò ìsara lọ́sòó.
cost:- iye owó, The cost of building is costly, Iye
owo ìkọ́lé ti wọ́n jù.
costume:- aṣọ eré. The actors need costume, Àwọn
òsèré nílò aṣọ eré.
cot:- ìbusùn ọmọdẹ, I bought a cot. Mo ra ìbusún ọmọde.
cottage:- àgọ́, Farmas live in cottage. Àwọn àgbẹ́ n
gbe ni àgọ́.
cotton:- òwú, clothes made from cotton, ara owú la n
ti n aṣọ.
cotton stainer:- kòkòrò òwú.
cotton wool:- òwú tutu, They use cotton wool in the
hospital. Wọn n lo owu tutu ni ile ìwòsàn.
couch:- àga ìrògbún, I sat on couch, Mo jókòó lórí aga
ìrògbún.
cough:- ikọ́. He has a cough. Ó ní àrùn ikọ́.
could:- kò. He could not do it, kò le sere.
council:- ìgbùmọ̀. The council met, Àwọn ìgbímọ̀
pàdé.
councilor:- ọmọ ìgbìmọ̀. He is a councillor, Ó jẹ́ ọmọ
ìgbìmọ̀.
count:- kà, He can count it, ó le kàá.
countable:- asònkà:- Goat is countable, Ewurẹ jẹ
asònkà.
counter:- tabili tó wa láàrin olùtajẹ̀ ati olùrajà.
contry:- orílẹ̀ ede
kan. Nigeria is a
country Náìjíráì jẹ orilẹ èdè kan.
country man:- ọmọ orílẹ̀ èdè kan.
couple:- ọkọ ati ìyàwó, kọ́lá ati Ayọ jẹ okọ ati
ìyàwó kọla and Ayọ are couple
coupon:- iwe tẹ́tẹ́, I saw a coupon, Mo n iwe tẹ́tẹ́.
courage:- níyànkú, He is couragers, o níyánjù.
course:- àkókò ti a lo fun nkankan.
court:- Ilé ẹjọ́. I took him to the court, Mo gbe lọ
si ilé ẹjọ.
counsion:- ọmọ egbọn mi obinrin, She is my
counsion. O jẹ ọmọ ẹgbọn mi.
cover:- bò, I cover my pot. Mo bo ìkòkò mí.
cover:- ìdérí, I use cover to cover by pot. Mo lo
ìdérí láti de ìkòkò mi.
cow:- Màlúù, They killed 2 cows, wọn pa màlúù meji.
coward:- ojo-He is coward: Ó jẹ́ ojo.
cowardice:- iwa ojo. He was cowardice, o jẹ ojo
ènìyàn.
cow boy:- adamálúù. Majority of fulanis is cow boy. Ọ̀pọ̀lọpọ̀
Fulani ni wọn jẹ adamálúù.
cow pea:- awújẹ́, I ate cowpea, Mo jẹ awujẹ.
cowrice:- owo ẹyọ, Our fore father used cowrice in
the olden day. Awọn baba nla wan a owó ẹyọ ní ayé àtijọ́
crab:- akàn. I like crab. Mó fẹ akàn.
crack:- là, The fruits crack, Èso ti là.
cradle:- Ibusu ipilẹ, I slept on cradle, Mo sun lorí
ìbusùn ìpílẹ̀
craft:- isé owó. Students mae craft. Ọmọ ilé-ìwé se
isẹ́ ọwọ́.
crafts – onise ọwọ, He is craftsman, O jẹ onísẹ́
awó.
cram:- ti pa típa. He cram tablet, o mi oògùn
tipátipá.
crane:- ero ìgbérù, They used crane to lift heavy
load. Wọn lo ero ìgbéru láti gbe ẹru tó wúwó.
crash:- forísapọ́n. The vechicle crashed. Ọkọ̀
forísánpọ́n.
crate:- àpótí, I bought 2 crate of numerals. Mo ra
apoti ọtí ẹlẹrin dodo méjì.
createn:- ilè lílu. The crash aeroplane createn, Ọkọ
òfurufú mún ki ilẹ̀ lu.
crawl:- fà, Baby craw, Ọmọ́dé máa n fà.
crayfish:- edé, I like crayfish, Mo fẹran edé.
crayon:- gègé aláwò. Pupuils use crayon, Àwọn ọmọ
ile iwe má n lo gègé aláwọ̀.
cream:- mílíkì ọlọ́rà. Children like cream. Àwọn ọmọde
fẹ́ràn mìlíkì ọlọra.
creater:- dá, God created man. Ọlọ́rún, dá ènìyàn.
creation:- dídá, The creation of earth. Dídá aye.
creature:- èdá, All creature is from God. Gbogbo ẹ̀dá
lati ọwọ ọlọ́run.
credit:- Mo ra oúnjẹ àwín.
creek:- sẹ́lẹ̀rú, I fetch creck. Mo pọn omi sẹ́lẹ̀rú
creep:- fà, The children creep. Àwọn ọmọdẹ n fà.
creepe:- àfòmó, creeper is not good for planetary àfómó
ko dára fún irúgbìn.
creepy:- ohun ẹru, Corps is creepy, òkú jẹ ẹlẹ́rù.
cresent:- àpẹẹrẹ osù túntun. There was a cresent
sign on flag. Apẹẹrẹ osu tuntun wa ni ara asia.
crest-iye ori ẹyẹ, Àwọn ẹyẹ maa ni iyẹ́ lóri.;The
bird has cresent
crew:- osise oko oju omi, My father is crew, Baba mi
jẹ òsìsẹ́ ọkọ oju omi.
criket:- eré ori papa kan. He played a criket. O se eré ori papa kan.
criket:- ìrẹ̀, I ate criket. Mo jẹ ìrẹ̀
crime:- ìwà ọ̀daran, Raping is a crime, fifapa ba obìnrìn
lo jẹ ìwà ọ̀daran.
cried:- súnkún. He cried. Ó sunkún.
criminal:- ọ̀daràn, He is criminal, ó jẹ́ ọ̀darán
crimson:- Irú àwọ kan, It has crimson colour.
cripple:- arọ, Government take care of cripple, Ijọba
ntọjú àwọn arọ.
crisis:- dàrúdàpọ̀. There was a crisis in the school.
Dàrúdàpọ̀ wa ní ilé-ìwé.
crisp:- gbẹ furu, Bread crisp, Búrẹ́dì ma ngbẹ
fúrú.
criticize:- sọ̀rọ̀ nipa, He criticize him. O sọrọ̀
nípa rẹ̀.
critic:- aláápọ́n, Dr Fọlarin was critic, Ọ̀mọ̀wé
Folarin jẹ aláápọ́n.
critical:- lile. The work is critical, ise náà jẹ
líle.
criticison:- àwíjàre, I heard all his criticision, Mo
gbọ́ gbogbo àwíjàre.
croak:- dún. Buds croak. Àwọn ẹyẹ dun.
crokery:- Àwọn ohun elo amọ! Crokery is made of day.
A n se awọn ohun elo amọ láti.
crocodite:- òònì crocodile lives inside water. Óòni n
gbe inú omi.
crooked:- wíwó, The dog’s leg crooked. Wíwó ni ẹsè
ajá wó.
crop:- irugbin, I planted a crop. Mo gbin irúgbìn.
cash crop:- irughin tita. Cocoa is one of the cash crop. Koko jẹ ọkan
nínú irugbin lítà.
cross:- àgbélèbu; Everybody has his now cross. Ẹ̀nìkọ̀ọ́kan
ló nì àgbélèbú.
cross:- kọjá. We crossed to the other side. A kọjá
si òdì kejì.
cross road:- oríta. There were a cross roads at Ifẹ.
Àwọn orita pọ ni Ile-Ifẹ.
crouch:- ká. He has a cruch back, Ó ní ẹ̀yín tó ká
crow:- dún àwọn àkùkọ ma n dún. The cock crows
crust:- òde. You have a hard.
crust, O ni ẹ̀yìn tó le
crutch:- kọ́mọ n rìn. He has been using crutch. O ti
n lo kọ́mọnrìn.
cry:- sunkún, He cry for help. O sunkun fún ìránlọ́wọ́.
cry stal:- dínngí oniyanrain, He has crystal. O ni
dinngí oníyanrìn.
cub:- onígunmẹ́rin, He bought a cube sugar. Ó ra súgà
onígunmẹ́rin.
cubic:- òdiwọ̀n,
cucumber:- èso kan,
I ate cucumber. Mo jẹ èso kan.
cuddle:- fa, I cuddle my wife, Mo fa ìyàwó mọ́ra.
cuft:- ọrùn ọwọ aṣọ, I have tight cuff, orùn owọ̀
aṣọ mi fún mi.
cultivate:- dá’ I cultivate a land. Mo dá oko.
cultivation:- dídá, I have a cultivation land, Mo ni
oko ti a ti da.
culture:- àsà Yoruba has many culture, Àwọn Yorùbá ni
àsà tó pò.
cultural:- egbẹ́ alásà. We have a cultural troupe. A
ní egbẹ́ alasà.
cuning:- ẹgbọn èwé, He is a cuning, ó ní ọgbọ́n
èwé.
cup:- Ife,
I used a cup. Mo lo Ife.
cupboard:- àpótí nlá, I kept my cloth inside
cupboard. Mo ko aṣọ mi sínú àpótí.
cure:- wòsàn. He has be cured. Wọ́n ti wósàn.
curfew:- kónílégbélé. There was a curfew, ofin
kónúlégbélé wà.
curious:- nifẹ, I have curious to Nigeria made.
Mo nifẹ si ohun ti Nigeria.
curiosity:- mínifẹ.
curl:- ká, snake curl, Ejo máa nka.
currency:- owó pépà, I gave him N20.00 currency, Mo
fun ni owó pépà ogún náírà.
current:- sísàn, The current of the water is too much,
sísàn omi náà pọ́jù.
cument:- lọ́wọ́lọ́wọ́, It is good to be current. Odara
lati mọ ohun to n lọ lọ́wọ́lọ́wọ́.
curry:- ẹ̀ròjà oúnjẹ, I add curry to my rice, Mo fi
eroja si ìrẹsi mi.
curse:- ègún; There is a curse on him egun wa lórí rẹ.
curve:- yi, The water curve the town. Omi yi ìlú ka.
curtain:- aṣọ ojufèrèsé, There was curtain on my window.
Aṣọ wa ni oju fèrèsè mi.
cushion:- tìmù tìmù, I use cushion to sit, Mo fi tumù
tùmù jó kòó.
custom:- àsà, It is my custom to sleep in the
afternoon. O jẹ àsà fún mi láti má sùn ni ọ̀sán
customary:- asasise, it is custormary, Ó jẹ́ àsà síse
customer:- olúraja, I have a custormer. Mo ní olùrajà.
cut:- gé, I cut grass. Mo ge koríko.
cut:- ọgbẹ́. I have a cut. Mo ni ọgbẹ́.
cutlass:- àdá. I bought a cuttlass, Mo ra àdá.
cutlery:- ohun èlò ìjẹ̀un. We have vuttlery at dinning
room, Ao ni ohun elo ìjẹun ni iyara ibi ìjẹun.
cuttle fish:- orísìí ẹja kan.
cycle, gùn I
cycle a bicycle. Mo gun kẹ̀kẹ́.
cylinder:- àgbá to sẹ́nu sónsó.
cyst:- ètútú, I have cyst on my leg. Mo ni ètútú ni ẹsẹ
daddy:- baba, I have daddy, Mo ni bàbá.
dagger:- ọbẹ, I used dagger to killed snake, Mo lọ
ọbẹ láti pa ejo.
daily:- ojoójúmọ́, sun rises daily, Ojóójumọ̀ ni oòrùn
n yọ
daily:- iwé ìróyín, I bought daily, Mo ra ìwé ìròyin.
dairy:- oko wàrà, My father has dairy, Bàbá mi ni oko
wàrà
dam:- adágún Government consuruct a dam. Ìjọba se omi
adágún
damage:- bajẹ, The bridge has damage. Afárá ti bàjẹ́.
damage:- ibajẹ, The damage of maize is too much,
ìbàjẹ́ àgbádo ti pọ púpọ̀.
damfo:- bole kájà. My father bought a damfo. Bàbá mi
ra ọkọ bólè kájà.
damp:- ẹrọ̀fó: He built on damp, ó kọ ile si ilẹ̀
eròfò.
dance:- jo, He danced till day break. O jo titi ilè fi
mó
dame gun:- ìbọn, I bought a dane gun. Mo ra ìbọn
danger:- ewu, There is a danger on the road. Ewu wa ni
ọ̀nà
dare:- gboya, he dare to kill the snake, ó laya láti
pa ejò.
dark:- sóòkùn, The room is dark iyàrá náà sóòkùn.
dark:- òkùnkùn, I can not see in the dark, emi ko le
ríran nínú òkùnkùn.
darling:- olólùfẹ́. I love my darling, Mo fẹ olólùfẹ́
mi
dart:- kánkán, The worker done the work dart. Àwọn
òsìsé se isé náà kánkán.
dash:- ààlá, There was a dash between him. Ààlà wa
láàrin wọn.
date:- iye ọjọ, what is today’s date kọ́ni iye ọjọ́
òní?.
daughter:- ọmọbìnrin. I have a daughter. Mo ni ọmọbìnrin
kan.
dawn:- kanri, The day is dawn. Ọjọ́ kanrí
day:- ojúmọ́, The day is good, ojúmọ́ òní dára.
day time:- ojúmọ́mó. We went to the school at day
time. A n lọ ilé ìwé ni ojúmọ́mà.
day:- to-day-ojoojọ́, There is day-to-day activities,
Àwọn àkànse ọjọ ọjọ́ wọ̀.
dead:- òkú. I saw a dead. Mo n òkú.
deadly:- atọ́kùn ikú – it is deadly place. Ó jẹ́
atókùn ikú
deaf:- adití. He is deaf. Ó jẹ́ adítí.
deal:- isé, I have a deal, Mo ni isé.
dealer:- álágbàtà, He is a motor dealer, O jẹ
alágbàtà mọto.
dear:- olúfẹ̀. My dear wife, olùfẹ́ ọ̀wọn iyàwó.
dear:- ọ̀wọn, I bought my car at dear price. Ọwọn
gogo ni mọ ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́
death:- Iku, death put an end to everything. Iku mu
opin ba ohun gbogbo.
debete:- ìjíròrò. They debated on the development of
the town, Wọn se ìjíròrò lórí ìdágbàsókè ìlú wọn.
debe:- ohun elo ipọn mi ni. Guusu Aafirika. I fetch
water with debe.
debt:- gbèsè. The man own debt.Ọkunrin náà jẹ gbèsé.
decade:- ọdun mẹ́wàá sẹ́yìn, He has died a decade
ago. Ó to ọdún mẹ́wàá tó ti kú.
decay:- rà, It is decay, Ó ti rà.
decay:- ìdíbàjẹ́, The meat has decay. Ẹran náà ti
díbàjẹ́.
deceive tànjẹ, He deceived me. O tán mi jẹ
deceiful:- òpùrọ́, He is a deceiful, Ó jẹ́ òpùrọ́.
december:- osù kejílá. I will funish by December. Ma
parí nínú osu kejìlá.
decent:- dára, He has a decent wife, O ni ìyàwó to
dára.
decide:- pinnu, He decided, Ó pinnu.
decision:- ipinnu, He took a decision, Ó se ìpinnu.
deciduous:- wówé, The tree deciduous, Àwọn igi nwọ́wé.
decimal:- onka.
deck:- ibijoko nínú okọ̀ ojú omi, I sat inside deck.;
Mo jòkòó nínú ọkọ̀ ojú omi
declare:- kéde, I declared him as a winner, Mọ kéde
rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi olùborí.
decline:- dínkù. Education is decling. Eto ẹkọ n
dínkù.
decorate:- selọ́sọ̀ọ́, They decorated him, Wọn se lọ́sọ̀ọ́.
decoration:- ọ̀sẹ́, There are lot of decoration at the
palace. Àwọn ọ̀sọ́ pọ ni ààfìn.
decrease:- dínkù, Their number of students is
decreasing. Iye àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti n dínkù.
deed:- ìse, I love his deed, Ìse rẹ n wu mí.
deep:- jìn, The river is two deep, Odo náà jin lópò.
dept:- jínjìn, the dept of the water is 8 feets,
jínjìn omi náà to ẹsẹ̀ mẹ́jọ.
deer:- agbanrere. Hunte killed a deer. Ọdẹ pa
agbanrere.
deaft:- borí, I deaft my enemy. Mo borí ọta mi
defence:- àbò, Defence is very important. Abo se
pàtàkì
deficievery:- àìnító important.
definite:- ero, I have definite for my journey. Mo ni
èrò fun irin ajo mi.
define:- túmọ̀, I define the word. Mo túmọ̀ ọ̀rọ̀ náà.
defy:- fojudi, Don’t defy the constitution, Ma se
fojudi ofin ile.
definance:- ìfojúdi, Her mother corrected her for
definance, Iya rẹ ba wi fun iwa àjojúdi.
degree:- òdiwọ̀n fun abajade ilé eko gigẹ. He has
degree in education, O ti gba oye igunlẹ nínú ìwe.
delay:- ìdíwọ́, There was delay along the road, ìdíwọ́
wà ní ọ̀nà.
delegate:- asojú, Delegate went to Àbíjá. Àwọn asojú
lọ sí Abùjà.
delegation:- Àwọn asojú, lọ.
delicate:- ẹlẹgẹ, Egg is delicate, ẹlẹgẹ ni ẹyin.
delicious:- àdídùn, I ate delicious food. Mo jẹ ounjẹ
àdídùn.
delight:- dùn, I was delighted to see you, Inú mi dùn
láti rí ọ.
delight:- inúdidun, They met him in delight, inúdídùn
ni wọ́n fi pàde rẹ̀.
deliver:- jísẹ, I deliver to him, Mo jíṣẹ́ fún un.
deliver:- bí, she has delivered, o ti bi.
delta:- ẹnúkò omi.
deluge:- ómíyalẹ́, There was deluge after rain,
omiyale lẹyìn àrọ̀dá òjò.
demand:- tọrọ, I demand from him. Mo tọrọ lọwọ
rẹ.
democracy:- ìjọba tìwatìwa. I like democracy, Mo fẹ́ràn
ìjọba tiwantiwa.
democratic:- Ìjọba awaarawa, Democratic system of
government is good, ìjọba awaarawa dára.
demolish:- wó. The government demolished some houses,
Àwọn ìjọba wo àwọn ilé kan.
democation:- wiwo, There was a democation in Àbújá.
Wiwo ile wa ni ìlú Àbújá
demonstrate:- se opẹẹrẹ, the teacher demonstrated
to the students, olùkọ́ se apẹẹrẹ fún Akẹ́kọ̀ọ́.
den:- Ibùgbé ẹranko. Lion lives at den., Kinniun n
gbe ibùgé rẹ.
dense:- nípọn,iron, dense to plank. Irin nipọn ju
páko lọ.
density:- Nínípon.
dentist:- Dókítà eyin. I visited a dentish. Mo lọ ri Dókítà
egín.
deny:- sẹ́, He deny her, ó sẹ́ ẹ́.
depart:- yà/gbéra, The vehicle departs at 6, Ọkọ̀ náà
gbéra ní agogo mẹ́fà.
depature:- lílọ, The depature of aeroplane made me to
travel by road. Lílọ ọkọ bàlúù mu ni lọ wọkọ̀.
department:- ẹka, I went to Yorùbá Department, Mo lọ
si ẹka èdè Yorùbá.
depend:- fara ti, I depend on God. Mo fara ti Ọlọ́run
dependant:- olùbọ́, I have four dependents. Mo ni
olùbó mẹ́rin.
deposit:- owó ásansílè, I have paid a deposit, Mo ti
san owó àsànsílẹ̀.
depot:- àká, There was a petrol depot. Aka epo petíróòlù
wà.
No comments:
Post a Comment