1.
Chance - (Àǹfààní)
Noun, Verb, Adj[1].
English Usage: It was a chance I have been waiting for
Yorùbá Usage: Ó jẹ́ àǹfààní tí mot i ń dúró dè
2.
Cheap – (Pọ́ọ́kú,
ṣ e àìwọ́n) Adj. Adv.
English Usage: Ade bought a cheap cloth for his brother’s
wedding ceremony
Yorùbá Usage: Adé ra aṣọ olówó pọ́ọ́kú fún ìgbéyàwo ẹgbọ́n
rẹ̀
English Usage: The goods that I bought in Onitsha market is
very cheap
Yorùbá Usage: Àwọn ọjà tí mo rà ní ọjà Ònìṣà kò wọ́n
3.
Cheese – (Wàràǹkàsì)
Noun
English Usage: The cheese is good for child to eat
Yorùbá Usage: Ó dára fún ọmọdé láti máa jẹ wàràǹkàsì
4.
Chemical – (këmíkà)
Noun
English Usage: Dada pour acidic chemical on Kúnlé’s body
Yorùbá Usage: Dàda da Kẹ́míkà olóró sí ara Kúnlé
5.
Chest – (Àyà)
Noun
English Usage: The bullet enter his chest
Yorùbá Usage: Qta ìbọn náà wọ inú àyà rẹ̀
6.
Chief – (Olóyè/Olórí)
Noun
English Usage: He was appointed a chief.
Yorùbá UsageWọ́n yàn án ní olóyè.
English Usage: The chief of the armed robbers was caught
last week
Yorùbá Usage: Wọ́n mú olórí àwọn olè náà ní ọsẹ̀ tí ó kọjá
7.
Chin (Àgbọ̀
ìsàlẹ̀) Noun
English Usage: My chin is paining me
Yorùbá Usage: Àgbôn ìsàlê mi ń dùn mí
8.
Church – (Ilé ìjọsìn)
Noun
English Usage: The woman prayed in the church
Yorùbá Usage: Obìnrin náà gbàdúrà nínú ṣọ́ọ̀sì
9.
Circle – (Òlóbìrípo)
Noun
English Usage: We sat in a circle
Yorùbá Usage: A jókòó ní olóbìrípo
No comments:
Post a Comment