1. TRUE
(i) (ADJ/AJ) Òtítọ́[1]:
Sọ bóyá òtítọ́ ni àwọn
ọ̀rọ̀ wọ̀nyí tàbí irọ́
Indicate whether the
following statements are true or false
S̟e òtítọ́ ni pé ó ń
lo̟?
Is it true she is leaving?
Gbogbo àwo̟n àheso̟ ọ̀rọ̀
náà padà jé òtítọ́
All the rumours turn out
to be true
Ìtàn òtító̟ ní iwé ìtàn-aroso̟
naa da le lori
The novel is based on a
true story
(ii) (ADJ/AJ) Gan-an:
Ohun gan-an
ti ojú ogun jẹ́
The true
face of war
Àkóbá gan-an tí àyẹ̀wó yí ṣe fún àyíká kò le di
mímò̟ fún ò̟pò̟lo̟pò̟ o̟dún sí àsìkò yí
The true cost of these experiments to the
environment will not be known for years to come.
Ó s̟e
àfihàn ìwà rè̟ gan-an fún àwo̟n ènìyàn díẹ̀ péré
He reveals his character
to very few people
(iii) (ADJ/AJ) Lóòtító
Lóòtító̟ ni pé ó lé s̟is̟e̟ náà, ṣùgbó̟n
ṣé ó lè wá nì íbamu pè̟lú àwon òs̟ìs̟é tí ó kù?
ENGLISH: It’s true that he could do
the job, but would he fit in with the rest of the team?
A lè ri i ní
è̟dínwò; lóòtító̟ ṣùgbón ṣe ò lè fi bé̟è̟ dára?
We would get
it cheaper; true, but would it be as good
(iv) (ADJ/AJ) Déédéé
Fíìmùnáà
kò se déédéé pèlú ìwé náà
The movie is
not true to the book.
(v) (ADV/AP)
Ò̟gangan
Lójú ìlà
tí ó lọ tààrà ofà náà fò ó sì s̟e ògangan ibi tí ní lọ́kàn
In a direct
line, the arrow flew straight and true to the target
2. TRICK
(i) (NOUN/OR) Ẹ̀tàn
Wọ́n ní láti
ronú ọ̀nà ètàn kan tí yióò mú wọn ko̟já àwo̟n olùsọ́gbà náà.
They had to
think of a trick to get past the guards
Ètàn:
Àwo̟n
aké̟kò̟ó̟ ń fi gbogbo ìgbà lo ètàn pè̟lú olùkó̟ wo̟n
The kids are
always playing tricks on their teacher.
(ii) (NOUN/OR) Irújú:
Ò̟kan lára
àwo̟n ìsò̟ro̟ o̟jó̟ ogbó ni pé okun ìrántí rẹ lè fa ìrújú fún o̟.
One of the problems of the old age is that your
memory can start to play tricks on you
Ǹje̟
e̟níké̟ni dúró síbè̟ tàbí ìrújú tí ó ga jù lọ ni?
Was there
somebody standing there or was it a trick of the highest?
(iii) (VERB/IṢ) Tàn:
Ó ti tàn
mí mo sì di ò̟dè̟
I have been
tricked and I felt stupid
(iv) Ó dógbó̟n tan e̟lè̟s̟ó̟ó̟ ààbò kí ó le
rí ònà ko̟já
He managed
to trick his way past the security guards
3. TROUBLE
(i) (NOUN/ OR) Ìṣòro
Rírí
òs̟ìs̟é̟ jé̟ ìṣòro fún wa
We have
trouble getting staff
Ó lè fún
mí nì ìs̟òro tí ó bá fé̟
He could
make trouble for me if he wanted to
(ii) (NOUN/OR) Dídùn/Dídà láàmú:
È̟yìn
dídùn
Back trouble
Dídà láàmú
ni orúnkún mi ń dà mí láàmú
I have been
having trouble with my knee
(NOUN/OR) Líle/Wàhálà:
Ilé is̟é̟ náà kojú àkókò líle koko ní
ibè̟rè̟ pè̟pè̟ nígbà tí ọ̀jà pàtàkì tí àwọn kan fẹ́ẹ kò wáyé mọ́
The company ran into
trouble earlier on, when a major order was canceled.
Tí n kò bá parí èyí lásìkò, n ó wọ
wàhálà
If I don’t get this finished in tune I will
be in trouble
(iii) (NOUN/OR)
Ìdààmú / Làásígbò
Nkò fé̟ fí o̟ sí inú ìdààmú tí ó po̟
I don’t want to put you into a lot of trouble
N ó gbà á tí ó bá fé̟; yóò yo̟ é̟ nínú idààmú
lílo̟ sí ìta
I will get it if you like; that save you the trouble of
going out
Ó la ò̟pò̟ làásígbò ko̟já kí ó tó lè wá ìwé
náà fún mi
She went to a lot of trouble to find the book for me
(iv) (VERB/IṢ)
Porúúruù:
Kí ni ohun tí ó porúúruù o̟kàn re̟
What is it that’s troubling you?
(v) (VERB/IṢ)
Dùn
È̟yìn mi tún ti ń dùn mí
My back has been troubling me again
(vi) (VERB/IṢ)
Ìyo̟nu
Ó
wo̟ inú iyàrá náà ní ìgbóná-gbóoru láìs̟e ìyo̟nu láti kàn ilè̟kùn
He rushed into the room without troubling to
knock on the door.
4. TROUSERS
(i) (NOUN
/OR) S̟òkòtò
Ṣòkòtò pénpé sì wà ní ìdí mi
I was still in short trousers
Ó ju
sòkòtò gígùn rè̟ sílè̟
He dropped
his trousers
5. TURN
(i) (VERB/ IṢ) Yí
Àwo̟n
àgbá o̟kò̟ náà bẹ̀rẹ̀ síí yí
The wheels
of the car began to turn.
Ó yí
àgbá náà kíákíá sí apá òsì
She turned
the wheel sharply to the left
(ii) (VERB/IṢ) Yí padà
A yí padà
a sì ko̟rí sílé
We turned and headed for home
Ó yí padà
láti wò mí
She turned
to look at me
Ó yí padà
sí is̟é̟ rè̟
He turned
back to his work
(iii) (VERB/IṢ) Yí
Ó yí àga
náà sí è̟gbé kí o le tún un s̟e
She turned
the chair on its side in order to repair it
Yí súẹ́tà
náà dà sí òdì kí o tó fò̟ ó̟
Turned the
sweater inside out before you wash it
(iv) (VERB/IṢ) Yà
Ònà náà yà si apá òsì tí abá kojá
ṣọ́ọ̀ṣì náà
The
road turns to the left after the church
(v) (VERB/IS) Dojú kọ
Àwo̟n
oló̟pàá dojú ibo̟n ojú-omi ko̟
àwon alájàngbilà náà
The Police turn
the water cannon on the rioter
Ó dojú
ìbo̟n ko̟ ara rè̟
He turned
the gun on himself
(vi) (VERB/IṢ) Pòyì
Ìsàn omi
náà ń pòyì, ó yẹ ká paadà
The tide is
turning, we should get back
(vii) (VERB/IṢ) Ká
Ó ká as̟o̟
ìbùsùn rè̟ sílẹ̀ ó sì bo̟ sí orí ìbùsùn
She turned
down the blanket and climbed into bed
(viii) (VERB/ IṢ) Padà:
Ewé náà
ti ń padà di dúdú
The leaves
were turning to black
Ó pínnu
lati padà di akọ́ṣẹ́mọṣẹ́
He decided
to turn professional
Agbẹjọ́rò
ni kí ó tó padà di olóṣèlú
He is a
lawyer turned politician
(ix) (VERB/IṢ) Dàrú
Nígbà tí
inú rè̟ dàrú, ó ṣe é bíi kí ó bì
When his
stomach turns, he feels as though to vomit
(x) (NOUN/ OR) ìyànà
Ò̟nà náà
kún fún ìyànà púpò̟
The road is
full of turns
(xi) (NOUN / OR) Àyipadà
Àyipadà
búburú ti dé bá ìlera rè̟
His health
has turned for the worse
(xii) (NOUN / OR) Asikò
Nígbà tí
ó bá di àsìkò tìre̟, kí ó o mú àwò̟ miíràn
When it’s
your turn take another colour
(xiii) (NOUN /OR)
Ìrìn yípo
A rìn
ìrìn yípo ibùdó náà
We took a
turn around the park
6. TWIST
(i) (VERB / IṢ) Ró./tẹ̀
Tẹ irin
náà ro̟ kí o fi ṣe àga
Twist the
iron to form a chair
(ii) (VERB/IṢ) Fà/rún
Ó mú mi ó
sì fa o̟wó̟ mi séyìn
He grabbed
me and twisted my arm behind my back
Ìbínú
rún ojú rè̟ pò̟
Her face
twisted in anger
(iii) (VERB /IṢ) Yí
Ó ń yí
ojú rè̟ kiri kí ó lè wò ó lójú
He twisted
his head around to look at her face
(iv) (VERB/IṢ) Ló̟ bíírí
Mo ló̟ bíírí
mo sì tún yí padà kí o̟wó̟ má bàa tẹ̀ mí
I twisted
and turned to avoid being caught
Ó tíraka,
ló̟ bíírí nínú àyè tó fún náà
He manage to
twist himself round in the restricted space
(v) (VERB / IṢ) Yii
Pe̟lu
ìbè̟rùbojo, mo yí òrùka náà tí ó wà níní ìka ọwọ́ mi
Nervously, I
twisted the ring on my finger
(vi) (VERB / IṢ) Ró̟
Ó s̟ubú
orúnkún rè̟ sì ró̟
He fell and
twisted his ankle
(vii) (VERB / IṢ) Wé
Ó wé
ìbòrí yípo orí rè̟
She twisted
a scarf around her head
Ejò kan wé
mọ́ ọn ní orùn o̟wó̟
A snake was twisted around
his arm
(viii) (VERB /IṢ) Yí
Ó ma ń fi
gbogbo ìgbà yí gbogbo ohun tí mo bá so̟ po
You always
twist everything I say
Wó̟n fi
e̟sùn kan ìwé ìròyìn náà pé ó ma ń yí òtítọ́ po
The newspaper was accused of twisting the
facts.
(ix) (NOUN/ OR) Yíyí
Yíyí ni ó
yí ìdérí náà lé̟è̟kan sí i, ó sì s̟í
She gave the
lid another twist and it came off.
7. UMBRELLA
(i) (NOUN/ OR) Agboòrùn
Mo ga agboòrùn
mi
I put up my
umbrella
Agboòrùn
aláwò̟ púpọ̀
Colourful
umbrella
(ii) (NOUN/ OR) Àsíá
Ò̟pò̟lo̟pò̟ egbé tí wó̟n yapa láìpé̟ yìí
ti papò̟ láti jùmò s̟e pọ̀ lábé̟ àsíá às̟e̟ kan náà
Many previously separate groups are now operating
under the umbrella of a single authority
8. UNDER
(i) (PREP/AT) Abé̟
S̟é̟ o ti
wo abé̟ ìbùsùn náà?
Have you
looked under the bed?
(ii) (PREP /AT) Ìsàlè̟
O̟kò̟ ojú
omi náà wà ní ìwọ̀n ò̟pò̟lo̟pò̟ e̟sè̟
bàtà ní ìsàlè̟ odò
The boat lay
under several feet of water
(iii) (PREP / AT) Lábé̟
Lákòókò
yìí orílè̟ èdè náà wà lábé̟ òfin
àwo̟n ológun
The country
is now under the martial law
Ó ní
àwo̟n òs̟ìs̟é̟ mó̟kàndílógún tí ó ń s̟is̟é̟ lábé̟ re̟
She has a
staff of nineteen working under her
(iv) (ADV / AP) Lábé̟
Ó mí
kanlè̟ osi wa labe̟ omi fun is̟ejú kan
She took a
deep breath and stayed under water for a minute
(v) (ADJ /AP): Abẹ́
Omi abé̟
igi
The water
under the tree
E̟ja abé̟
omi
The underwater
fish
9. UNIT
(i) (NOUN /OR) Ìdá
Ìdá kan tí ó
jẹ́ ìpìlẹ̀ ni ebí jé̟ ní àwùjo̟
The basic
unit of society is the family
(ii) (NOUN / OR) È̟ka
È̟ka igbebi
áláboyún kan
A maternity
unit
(iii) (NOUN / OR) Ìwò̟n
Wọ́ fún àwọn obìnrin nímọ̀ràn pé kí won máà mu
ju ìwò̟n mé̟rìnlá ògógóró lo̟ ló̟sè̟
Women are advised not to drink more than fourteen
units of alcohol per week.
(vi) (NOUN / OR) Abala
Abala ibi tí
ó ń múṣẹ́ ṣe nínú kòmpútà náà
The central
processing unit of a computer
10. UP
(i) (ADV / AP) Lo̟ / Soke:
Ó fò
sókè láti orí àga ìjókòó rè̟
He jumped up
from his chair
Wón ń gbé lókè orí
ókè náà
They live up in the
mountain
Máa bọ̀ lókè
Up you come
(ii) (ADV / AP) Yé̟le̟yè̟le̟
Ó fa bébà
náà ya yé̟le̟yè̟le̟
She tore the
paper up
(iii) (ADV /AP) Patapata
A je̟ gbogbo
óúnje̟ náà pátápátá
We ate all
the food up
Odò náà
gbe̟ pátápátá
The stream
has dried up
(iii) (ADV / AP) jọ
Ìjo̟ba ti gbà
láti kó ìgbìmò̟ às̟e ìwádìí jo
The
government agreed to set up a committee of inquiry
Ó kó àwon
ohun ìní rè̟ jo̟
She gathers
up her belongings
(iv) (ADV / AP) ná
Mo ní àwon
is̟é kan láti parí ná
I have some
work to finish up
(v) (ADV / AP) Pinpin
Dé kòòtu
re̟ pinpin; òtútù ń mú
Do your coat
up; it is cold
(vi) (ADV / AP) Dáadáa
Ó pé
dáadáa ki n tó sùn ní alẹ́ àná
I stayed up
late last night
(vii) (PREP / AT) Ní òkè
Abúlé náà
wà ní iwájú ní óké ò̟gbun náà
The village
is further up the valley
(viii) (ADJ / AP)
Òkè
Eranko òkè
ni ò̟bo̟ jé̟
Monkey is an
up animal
(ix) (VERB /IṢ) Dìde
Ó dìde ó sì lo̟
ní òjijì láìso̟ fún e̟niké̟ni
He upped and
left without telling anyone
(x) (NOUN / OR) As̟eyọrí
E̟gbé̟ náà tí ǹ s̟e às̟eyọrí láti ìbè̟rè̟ pèpè
E̟gbé̟ náà tí ǹ s̟e às̟eyọrí láti ìbè̟rè̟ pèpè
The club has
been on the up since the beginning
No comments:
Post a Comment