Dókítà Adébùsọ́lá Ọnàyẹmí tí ó jẹ́ oníṣègùn Òyìnbó ni olùdásílẹ̀ BIS BUS INTERNATIONAL. Ó ti ṣe iṣẹ́ ribiribi láti gbé èdè Yorùbá lárugẹ, ní pàtàkì, fún àwọn tí ó ń kọ́ èdè náà kún tiwọn. Wọ́n máa ń fẹ́ rí ìwé àwọn tí ó bá ní ìfẹ́ sí èdè Yorùbá. Àdírẹ́sì BIS BUS INTERNATIONAL ni:
The Executive Director
BIS BUS INTERNATIONAL
40 Alana Drive
Barie Ontario
L4N 7K8 Canada
Tel: (705) 728-1697
Tel./Voice Mail/Fax: (705) 728-0980
Web site: www.learnyoruba.com
No comments:
Post a Comment