(i) (informal/gbẹ̀fẹ́) (v/IṢ): ba nnkan tàbí ẹni kan jẹ́; pa nnkan tàbí ẹni kan, ní pàtàkì, kí ó jẹ́ ohun tí a mọ̀-ọ́n-mọ̀ ṣe. Those weapons can zap many of their enemies. Àwọn ohun ìjà ogun yẹn lè pa púpọ̀ nínú àwọn ọ̀tá wọn.
(ii) (informal/gbẹ̀fẹ́) (v/IṢ): lọ sí ibi kan kíákíá; ṣe nnkan láìfi falẹ̀. He zapped through his assignments before we went shopping. Ó yára ṣe iṣẹ́ rẹ̀ kí á tó lọ ra nnkan ní ọja
(iii) (informal/gbẹ̀fẹ́) (n/OR): agbára; ọ̀yàyà. He put more zap into his performance. Ó tẹ ipá mọ́ ohun tí ó n ṣe sí i.
No comments:
Post a Comment